Sunday, August 26, 2012

Yoruba traditional religion

Ifa is the traditional religion of Yoruba people, notwithstanding centuries of oppression at the hands of colonizers. Ifa continued to survive, even the unspeakable horrors of enslavement. Wise leaders hid the religion behind a protective camouflage of Christian saints amd symbols. It assumes direct intellectual responsibility by the Yoruba for their collective history and culture; and extends the scope of Ifa studies in a new and original way and the truth that Africans both on the continent and throughout the diaspora are heirs to a glorious tradition, one whose origins stretch back into the primoridial mists of antiquity. Visit www.ifa.gnbo.com.ngÀWO N O MO  ODÙ
Léyìn àwon ojú odù méríndinlógún yìí, àwon òjìlérúgba odù míràn tún wà tí à ń pè ni omo odù tàbí àmúlù odù wón jé omo odù nitorí pé a gbà pé won se omodé si àwon ojú odù, à ń pè wón ni Àmúlù odù nítorí pé orúko odù méjì ni òkòòkan wón jé. F.A., èkíni nínú àwon odù wònyìí a máa je ogbeyèkú.Àwon Yoruba ka àwon odu wònyú si òòsà pàtàkì jùlo, àwon ojù odú. F.A. Ese-ifa òwònrín méjì
(a) Ikin níi fagbáríí seléÀtàrí ni o jóòrún ó pagbin ìsàlè
Olobonhunbonhun ni fapa ara re dá gbèdú. Lo si http://www.ifa.gnbo.com.ng/  fun alaye kikun.Sunday, August 5, 2012

Iwa (character) is one of or perhaps the most important human endeavor taught within Ifa literary corpus and every Ifa stanza (or verse) has one portion dedicated to the issue of teaching the Iwa (character or behaviour) that Ifa supports. This Iwa, which Ifa teaches transcends religious doctrine, is central to every human being, and imparts communal, social and civic responsibility that the Creator (Olodumare) supports. Central to this, is the theme of righteousness and practicing good moral behaviour, not seeking for it in the community but becoming an ambassador of Iwa. Visit www.ifa.gnbo.com.ng for more information.

Káàkìri àgbáyé ni a ti mò pé olódùmarè wà, eni tí ó dá ayé àti òrùn àti ohun gbogbo ti ń be nínú won òyígíyigí oba àìrí arínú-róde Olùmòràn Òkàn, alèwílèse, alèselèwí, Oba atélè bí eni téní, Oba atésánmo bí eni téso, Oba lónìí, Oba lóla, Oba títí ayé àìnípèkun, Olówó gbogbogbo tí ń yomo rè nínú òfin, Oba Olójú lu kára bí ajere, Oba onínú fúnfún. Visit www.ifa.gnbo.com.ng