Sunday, September 30, 2012

Olodumare

Olodumare or Olorun as the supreme, self-existing deity. According to author Bolasi E. Idowu:"He is supreme over all on earth and in heaven, acknowledged by all the divinities as the Head to whom all authority belongs and all allegiance is due. . . His status of supremacy is absolute. Things happen when He approves, things do not come to pass if He disapproves. In worship, the Yoruba holds Him ultimately First and Last; in man's daily life, He has the ultimate pre-eminence." Olodumare: God in Yoruba Belief
Ebo rírú se pàtàkì fún eni tí a bá dá ifá fún. bí ifá tí a dá fún ènìyàn bá se rere tàbí búbúru, oní tòhùn ni lati rúbo kí ohun tí ó dá ifá sí náà ó lè baà dará: lónà kìní:- Ebo ifá jé ounje fún òrìsà tí ifá bá so wí pé kí á rúbo, Fun àpeere, tí ènìyàn bá fé se nnkan. ti o ba bèrè lówó ifá, wón le so pé ki o lo rubo fun ògun, Ebo ifá jé ètùtù pàtàkì nítorí tí Babaláwo bání kí ènìyàn se nnkan óní láti se é, ki òun pàápàá ólè ba à ni ìgboyà wípé àteégún-àteésà, nítori èyí ní àwon babaláwo fi máa ńwí fún ení tí a ní kí ó rúbo pé kí ó wá oúnje fún àwon aládùgbóó re. Mimo mimo mimo Olodumare





Sunday, September 23, 2012

Oròrò Ifá

Oròrò Ifá - Narration or declaration; making a verbal authoritative declaration during the divination analysis or during the advisement following divination or prayer while performing appeasement. Click here for more details Grasping the Root of Divine Power: A spiritual healer's guide to African culture, Orisha religion, OBI divination, spiritual cleanses, spiritual growth ... and mind power (How to be an Afrakan)


Ifá jé agbòràndun fún gbogbo àwon òrìsà yókù. Bí eégún ilée baba eni ba féé bínú sí ni, láti odo ifá ni a ó ti gbò èyí wáá fún ifá ni ipo asojú fún gbogbo àwon irúnmolè yókù. Bí kò bá sí ifá, iyì àti olá ti àwon Yorùbá mbú fun gbogbo àwon òrìsà ilèe Yorùbá ró, tí ó sì nwà ońje sí won lénu.
Gégé bí a ti so síwájú, àwon omo òrúnmìlà ni òrúnmìlà fún ní ikin ifá mérìndínlógún nígbà tí ó padà lo si òrun tí ló sí wa sílé ayé mó.Mérìndínlógún: Òrìsà Divination Using 16 Cowries: Revised and Extended Edition





Sunday, September 16, 2012

Ìṣẹ̀ṣe

The name Ìṣẹ̀ṣe can be used to describe several things within the Yoruba tradition, Ìṣẹ̀ṣe is considered ones Progenitors, all the Primordial Beings of Creation are also Ìṣẹ̀ṣe, the collective of all the Orisa/and 201 Irunmole are Ìṣẹ̀ṣe, also Ìṣẹ̀ṣe is another term used to encapsulate this tradition of Ifa/Orisa as a whole.... Ìṣẹ̀ṣe also in this regard means Traditionalism.  For more information visit http://ifa.gnbo.com.ng/

Ninu asa Yoruba ni a ti ri irú ipò pataki ti Orìsà-nla tabi Obàtálá kó laarin awon òrìsà ati irúnmalè ni ile Yoruba. A ti gbó pelu pe jákè-jádò gbogbo ilè Yorùbá ni nwon maa mbó ó, nitoripe oun ni awon àgbà àtijó gbà ninu ìtàn ìsèdálè won pe o je igbákejì Olódùmarè, ti o si nràn an lówó lati tún enia dá nipa fífún un ni ojú, imú, eti, ati gbogbo èyà ara miran ti o ye ki èdá ní ki o fi lè di enia pipe. Lo si http://ifa.gnbo.com.ng/ fun aaye kikun.





Saturday, September 1, 2012

Believe

Fundamentals of the YORUBA RELIGION (Orisa Worship) Believers deem Ifa as being nothing but the "truth"; functioning to the devoted as not only a system of guidance, but one that fuses way of living with the psychological, providing them with a legitimate course of action that is genuine and unequivocal. African Religions & Philosophy (African Writers) Visit www.ifa.gnbo.com.ng for more information



Ifá jé òrìsà kan pàtàkì láàrin àwon Yorùbá. Àwon Yorùbá gbàgbó wí pé Olódùmarè ló rán ifá wá láti òde òrun latí wá fi ogbón rè tún ilé ayé se. Ogbón, ìmò, àti òye tí olódùmarè fi fún ifá ló fún ifá ní ipò ńlá láàrin àwon ìbọ ní ile Yorùbá. “A-kéré-finú-sogbón” ni oríkì ifá. òrùnmìlà fún àwon òmo rè ní ikin mérìndínlógùnÌkín.  Ìkín mérìndinógun náà ni à ń lò lòníí láti bèèrè nnkan lówó ifá.ILE IFA INTERNATIONAL: ORUNMILA'S HEALING SPACES  Lo si http://www.ifa.gnbo.com.ng/ fun alaye kikun.