Sunday, September 30, 2012

Olodumare

Olodumare or Olorun as the supreme, self-existing deity. According to author Bolasi E. Idowu:"He is supreme over all on earth and in heaven, acknowledged by all the divinities as the Head to whom all authority belongs and all allegiance is due. . . His status of supremacy is absolute. Things happen when He approves, things do not come to pass if He disapproves. In worship, the Yoruba holds Him ultimately First and Last; in man's daily life, He has the ultimate pre-eminence." Olodumare: God in Yoruba Belief
Ebo rírú se pàtàkì fún eni tí a bá dá ifá fún. bí ifá tí a dá fún ènìyàn bá se rere tàbí búbúru, oní tòhùn ni lati rúbo kí ohun tí ó dá ifá sí náà ó lè baà dará: lónà kìní:- Ebo ifá jé ounje fún òrìsà tí ifá bá so wí pé kí á rúbo, Fun àpeere, tí ènìyàn bá fé se nnkan. ti o ba bèrè lówó ifá, wón le so pé ki o lo rubo fun ògun, Ebo ifá jé ètùtù pàtàkì nítorí tí Babaláwo bání kí ènìyàn se nnkan óní láti se é, ki òun pàápàá ólè ba à ni ìgboyà wípé àteégún-àteésà, nítori èyí ní àwon babaláwo fi máa ńwí fún ení tí a ní kí ó rúbo pé kí ó wá oúnje fún àwon aládùgbóó re. Mimo mimo mimo Olodumare

No comments:

Post a Comment