Sunday, September 16, 2012

Ìṣẹ̀ṣe

The name Ìṣẹ̀ṣe can be used to describe several things within the Yoruba tradition, Ìṣẹ̀ṣe is considered ones Progenitors, all the Primordial Beings of Creation are also Ìṣẹ̀ṣe, the collective of all the Orisa/and 201 Irunmole are Ìṣẹ̀ṣe, also Ìṣẹ̀ṣe is another term used to encapsulate this tradition of Ifa/Orisa as a whole.... Ìṣẹ̀ṣe also in this regard means Traditionalism.  For more information visit http://ifa.gnbo.com.ng/

Ninu asa Yoruba ni a ti ri irú ipò pataki ti Orìsà-nla tabi Obàtálá kó laarin awon òrìsà ati irúnmalè ni ile Yoruba. A ti gbó pelu pe jákè-jádò gbogbo ilè Yorùbá ni nwon maa mbó ó, nitoripe oun ni awon àgbà àtijó gbà ninu ìtàn ìsèdálè won pe o je igbákejì Olódùmarè, ti o si nràn an lówó lati tún enia dá nipa fífún un ni ojú, imú, eti, ati gbogbo èyà ara miran ti o ye ki èdá ní ki o fi lè di enia pipe. Lo si http://ifa.gnbo.com.ng/ fun aaye kikun.

No comments:

Post a Comment