Saturday, September 1, 2012

Believe

Fundamentals of the YORUBA RELIGION (Orisa Worship) Believers deem Ifa as being nothing but the "truth"; functioning to the devoted as not only a system of guidance, but one that fuses way of living with the psychological, providing them with a legitimate course of action that is genuine and unequivocal. African Religions & Philosophy (African Writers) Visit www.ifa.gnbo.com.ng for more informationIfá jé òrìsà kan pàtàkì láàrin àwon Yorùbá. Àwon Yorùbá gbàgbó wí pé Olódùmarè ló rán ifá wá láti òde òrun latí wá fi ogbón rè tún ilé ayé se. Ogbón, ìmò, àti òye tí olódùmarè fi fún ifá ló fún ifá ní ipò ńlá láàrin àwon ìbọ ní ile Yorùbá. “A-kéré-finú-sogbón” ni oríkì ifá. òrùnmìlà fún àwon òmo rè ní ikin mérìndínlógùnÌkín.  Ìkín mérìndinógun náà ni à ń lò lòníí láti bèèrè nnkan lówó ifá.ILE IFA INTERNATIONAL: ORUNMILA'S HEALING SPACES  Lo si http://www.ifa.gnbo.com.ng/ fun alaye kikun.No comments:

Post a Comment